Hosia 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

N kò ní fa ibinu yọ mọ́,n kò ní pa Efuraimu run mọ́,nítorí pé Ọlọrun ni mí,n kì í ṣe eniyan,èmi ni Ẹni Mímọ́ tí ó wà láàrin yín,n kò sì ní pa yín run.

Hosia 11

Hosia 11:2-12