Hosia 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo ha gbọdọ̀ yọwọ́ lọ́rọ̀ yín ẹ̀yin Efuraimu?Mo ha gbọdọ̀ kọ̀ ọ́ sílẹ̀, Israẹli?Mo ha gbọdọ̀ pa ọ́ run bí mo ti pa Adimai run;kí n ṣe sí ọ bí mo ti ṣe sí Seboimu?Ọkàn mi kò gbà á,àánú yín a máa ṣe mí.

Hosia 11

Hosia 11:5-10