Heberu 10:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni meji tabi mẹta bá jẹ́rìí pé ẹnìkan ṣá Òfin Mose tì, pípa ni wọn yóo pa olúwarẹ̀ láì ṣàánú rẹ̀.

Heberu 10

Heberu 10:23-30