Heberu 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ohun tí ó kù ni pé kí á máa retí ìdájọ́ pẹlu ìpayà ati iná ńlá tí yóo pa àwọn ọ̀tá Ọlọrun.

Heberu 10

Heberu 10:17-35