Hagai 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí pé èmi, OLUWA àwọn ọmọ ogun ni mo sọ ọ́ pé láìpẹ́, n óo tún mi ọ̀run ati ayé jìgìjìgì lẹ́ẹ̀kan sí i, ati òkun ati ilẹ̀.

Hagai 2

Hagai 2:1-13