Habakuku 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Oòrùn ati òṣùpá dúró ní ipò wọn,nígbà tí ọfà rẹ ń já lọ ṣòòrò,tí àwọn ọ̀kọ̀ rẹ náà ń kọ mànà,bí wọ́n ti ń fò lọ.

Habakuku 3

Habakuku 3:3-18