Habakuku 3:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn òkè ńlá rí ọ,wọ́n wárìrì;àgbàrá omi wọ́ kọjá;ibú òkun pariwo,ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè.

Habakuku 3

Habakuku 3:8-12