Ẹsita 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsita bá dá a lóhùn pé, “Ọlọ̀tẹ̀ ati ọ̀tá náà ni Hamani eniyan burúkú yìí.” Ẹ̀rù ba Hamani gidigidi níwájú ọba ati ayaba.

Ẹsita 7

Ẹsita 7:1-10