Ẹsita 7:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahasu-erusi ọba bi Ẹsita Ayaba pé, “Ta ni olúwarẹ̀, níbo ni ẹni náà wà, tí ń gbèrò láti dán irú nǹkan bẹ́ẹ̀ wò?”

Ẹsita 7

Ẹsita 7:4-10