Ẹsita 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsita bá dáhùn pé, “Bí inú kabiyesi bá dùn sí mi, mo fẹ́ kí kabiyesi ati Hamani wá sí ibi àsè tí n óo sè fun yín ní alẹ́ òní.”

Ẹsita 5

Ẹsita 5:3-11