Ẹsita 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba bi ayaba Ẹsita pé, “Ẹsita, kí ló dé? Kí ni ẹ̀dùn ọkàn rẹ? A óo fún ọ, títí dé ìdajì ìjọba mi.”

Ẹsita 5

Ẹsita 5:1-7