Ẹsita 5:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Hamani pa á mọ́ra, ó lọ sí ilé rẹ̀. Ó pe gbogbo àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ ati iyawo rẹ̀ tí ń jẹ́ Sereṣi,

Ẹsita 5

Ẹsita 5:8-12