Ẹsita 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wà lára àwọn tí Nebukadinesari ọba Babiloni kó lẹ́rú láti Jerusalẹmu lọ sí ilẹ̀ Babiloni pẹlu Jekonaya, ọba Juda.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:1-14