Ẹsita 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan, ará Juda láti inú ẹ̀yà Bẹnjamini wà ní ààfin Susa, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Modekai, ọmọ Jairi, ọmọ Ṣimei, ọmọ Kiṣi.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:4-13