Ẹsita 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Modekai gbọ́ nípa ọ̀tẹ̀ náà, ó sọ fún Ẹsita, ayaba, Ẹsita bá tètè lọ sọ fún ọba pé Modekai ni ó gbọ́ nípa ète náà tí ó sọ fún òun.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:13-23