Ẹsita 2:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Lojoojumọ ni Modekai máa ń rìn sókè sódò níwájú àgbàlá ibi tí àwọn ayaba ń gbé, láti bèèrè alaafia Ẹsita, ati bí ó ti ń ṣe sí.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:1-14