Ẹsita 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹsita kò sọ inú ẹ̀yà tí òun ti wá, tabi ìdílé rẹ̀, fún ẹnikẹ́ni nítorí pé Modekai ti kìlọ̀ fún un pé kí ó má ṣe sọ nǹkankan nípa rẹ̀.

Ẹsita 2

Ẹsita 2:5-11