Ẹsira 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ọmọ Elamu, Jeṣaya, ọmọ Atalaya, ni olórí;orúkọ aadọrin eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:6-15