Ẹsira 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu àwọn ọmọ Adini, Ebedi, ọmọ Jonatani, ni olórí;orúkọ aadọta eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.

Ẹsira 8

Ẹsira 8:4-8