Ẹsira 7:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya,

2. ọmọ Ṣalumu, ọmọ Sadoku, ọmọ Ahitubu,

3. ọmọ Amaraya, ọmọ Asaraya, ọmọ Meraiotu,

Ẹsira 7