Ẹsira 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya,

Ẹsira 7

Ẹsira 7:1-3