Ẹsira 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Ahasu-erusi, àwọn kan kọ ìwé wọ́n fi ẹ̀sùn kan àwọn tí ń gbé Juda ati Jerusalẹmu.

Ẹsira 4

Ẹsira 4:1-16