Ẹsira 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gba àwọn olùdámọ̀ràn èké tí wọ́n ń san owó fún láti da ìpinnu àwọn ará Juda rú ní gbogbo àkókò ìjọba Kirusi, ọba Pasia, títí di àkókò Dariusi, ọba Pasia.

Ẹsira 4

Ẹsira 4:1-7