Ẹkún Jeremaya 5:21-22 BIBELI MIMỌ (BM)

21. Mú wa pada sọ́dọ̀ ara rẹ, OLUWA,kí á lè pada sí ipò wa.Mú àwọn ọjọ́ àtijọ́ wa pada.

22. Ṣé o ti kọ̀ wá sílẹ̀ patapata ni?Àbí o sì tún ń bínú sí wa, inú rẹ kò tíì rọ̀?

Ẹkún Jeremaya 5