Ẹkún Jeremaya 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjìyà àwọn eniyan mi pọ̀ ju ti àwọn ará Sodomu lọ,Sodomu tí ó parun lójijì,láìjẹ́ pé eniyan fi ọwọ́ kàn án.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:1-13