Ẹkún Jeremaya 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọn tí ń jẹ oúnjẹ àdídùndi ẹni tí ń ṣa ilẹ̀ jẹ kiri ní ìgboro.Àwọn tí wọn tí ń fi aṣọ àlàárì boradi ẹni tí ń sùn lórí òkítì eérú.

Ẹkún Jeremaya 4

Ẹkún Jeremaya 4:4-15