Ẹkún Jeremaya 3:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Èmi ni mo mọ bí eniyan tií rí ìpọ́njú,tí mo mọ bí Ọlọrun tií fi ibinu na eniyan ní pàṣán.

2. Ó lé mi wọ inú òkùnkùn biribiri.

3. Dájúdájú, ó ti dojú kọ mí,ó sì bá mi jà léraléra tọ̀sán-tòru.

Ẹkún Jeremaya 3