Ẹkún Jeremaya 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni mo mọ bí eniyan tií rí ìpọ́njú,tí mo mọ bí Ọlọrun tií fi ibinu na eniyan ní pàṣán.

Ẹkún Jeremaya 3

Ẹkún Jeremaya 3:1-3