Ẹkún Jeremaya 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìran èké ati ti ẹ̀tàn ni àwọn wolii rẹ ń rí sí ọ;wọn kò fi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ hàn ọ́,kí wọ́n lè dá ire rẹ pada,ṣugbọn wọ́n ń ríran èké ati ìran ẹ̀tàn sí ọ.

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:9-21