Ẹkún Jeremaya 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí ni mo lè sọ nípa rẹ,kí sì ni ǹ bá fi ọ́ wé, Jerusalẹmu?Kí ni mo lè fi wé ọ,kí n lè tù ọ́ ninu, ìwọ Sioni?Nítorí bí omi òkun ni ìparun rẹ gbòòrò;ta ló lè mú ọ pada bọ̀ sípò?

Ẹkún Jeremaya 2

Ẹkún Jeremaya 2:11-22