Ẹkún Jeremaya 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ohun tí ó tọ́ ni OLUWA ṣe,nítorí mo ti ṣe àìgbọràn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀;ṣugbọn, ẹ gbọ́, ẹ̀yin eniyan,ẹ kíyèsí ìjìyà mi;wọ́n ti kó àwọn ọdọmọbinrin ati ọdọmọkunrin milọ sí ìgbèkùn.

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:12-22