Ẹkún Jeremaya 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

“Sioni na ọwọ́ rẹ̀ fún ìrànwọ́,Ṣugbọn kò sí ẹni tí ó ràn án lọ́wọ́,OLUWA ti pàṣẹ pé,kí àwọn aládùúgbò Jakọbu di ọ̀tá rẹ̀;Jerusalẹmu sì ti di eléèérí láàrin wọn.

Ẹkún Jeremaya 1

Ẹkún Jeremaya 1:8-18