Ẹkisodu 9:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn pidánpidán kò lè dúró níwájú Mose, nítorí pe oówo bo àwọn náà ati gbogbo àwọn eniyan ilẹ̀ Ijipti.

Ẹkisodu 9

Ẹkisodu 9:10-16