Ẹkisodu 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose ati Aaroni bá bu eérú ninu ẹbu, wọ́n dúró níwájú Farao. Mose da eérú náà sókè sí ojú ọ̀run, eérú náà bá di oówo tí ń di egbò lára eniyan ati ẹranko.

Ẹkisodu 9

Ẹkisodu 9:9-15