Ẹkisodu 39:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Bẹ́ẹ̀ ni gbogbo iṣẹ́ àgọ́ àjọ náà ṣe parí, àwọn ọmọ Israẹli ṣe ohun gbogbo gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ẹkisodu 39

Ẹkisodu 39:28-38