Ẹkisodu 39:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n so aṣọ aláwọ̀ aró tẹ́ẹ́rẹ́ kan mọ́ ọn, láti máa fi so ó mọ́ etí adé náà gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún Mose.

Ẹkisodu 39

Ẹkisodu 39:23-36