Ẹkisodu 37:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ife mẹrin ni ó ṣe sórí ọ̀pá fìtílà náà gan-an, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dàbí òdòdó alimọndi pẹlu ìrudi ati ìtànná rẹ̀.

Ẹkisodu 37

Ẹkisodu 37:16-22