Ẹkisodu 37:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe àwọn kinní kan bí òdòdó alimọndi mẹta mẹta sórí ọ̀kọ̀ọ̀kan ninu àwọn ẹ̀ka mẹfẹẹfa tí ó yọ lára ọ̀pá fìtílà náà.

Ẹkisodu 37

Ẹkisodu 37:14-29