Ẹkisodu 32:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Joṣua ti gbọ́ ariwo àwọn eniyan náà tí wọn ń ké, ó wí fún Mose pé, “Ariwo ogun wà ninu àgọ́.”

Ẹkisodu 32

Ẹkisodu 32:13-24