Ẹkisodu 32:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Iṣẹ́ ọwọ́ Ọlọrun ni àwọn wàláà òkúta náà, Ọlọrun tìkararẹ̀ ni ó sì fi ọwọ́ ara rẹ̀ kọ ohun tí ó wà lára wọn.

Ẹkisodu 32

Ẹkisodu 32:9-23