Ẹkisodu 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn eniyan náà bá pa ohùn pọ̀, wọ́n ní, “Gbogbo ohun tí OLUWA wí ni a óo ṣe.” Mose bá lọ sọ ohun tí àwọn eniyan náà wí fún OLUWA.

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:5-17