Ẹkisodu 19:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá pada wá, ó pe àwọn àgbààgbà Israẹli jọ, ó sì sọ gbogbo ohun tí OLUWA pa láṣẹ fún un fún wọn.

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:4-12