Ẹkisodu 19:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá gòkè tọ Ọlọrun lọ.OLUWA pè é láti orí òkè náà, ó ní, “Ohun tí mo fẹ́ kí o sọ fún àwọn ọmọ Israẹli nìyí,

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:1-6