Ẹkisodu 19:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Refidimu ni wọ́n ti gbéra wá sí aṣálẹ̀ Sinai. Nígbà tí wọ́n dé aṣálẹ̀ yìí, wọ́n pàgọ́ wọn siwaju òkè Sinai.

Ẹkisodu 19

Ẹkisodu 19:1-8