Ẹkisodu 1:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn arọmọdọmọ Israẹli pọ̀ sí i, wọ́n di alágbára gidigidi, wọ́n sì pọ̀ káàkiri ní ilẹ̀ Ijipti.

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:1-9