Ẹkisodu 1:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, Josẹfu kú, gbogbo àwọn arakunrin rẹ̀ náà kú ní ọ̀kọ̀ọ̀kan títí tí gbogbo ìran náà fi kú tán.

Ẹkisodu 1

Ẹkisodu 1:1-11