Diutaronomi 8:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé ilẹ̀ dáradára ni ilẹ̀ tí OLUWA Ọlọrun yín ń mu yín lọ. Ó kún fún ọpọlọpọ adágún omi, ati orísun omi tí ó ń tú jáde ninu àwọn àfonífojì ati lára àwọn òkè.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:2-11