Diutaronomi 8:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ pa òfin OLUWA Ọlọrun yín mọ́, nípa rírìn ní ọ̀nà rẹ̀ ati bíbẹ̀rù rẹ̀.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:4-7