Diutaronomi 8:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ ṣọ́ra, kí ẹ má gbàgbé OLUWA Ọlọrun yín, nípa àìpa àwọn òfin ati ìlànà rẹ̀ mọ́, ati ìdájọ́ rẹ̀ tí mo fun yín lónìí,

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:7-20