Diutaronomi 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ẹ bá jẹun, tí ẹ yó, ẹ óo dúpẹ́ lọ́wọ́ OLUWA Ọlọrun yín fún ilẹ̀ dáradára tí ó fun yín.

Diutaronomi 8

Diutaronomi 8:8-11